Ifa

1
Ifá Oríkì Ifá (Recitada en el momento de consulta, para que Ifá oriente al adivino) Òrúnmìlà Ajànà Ifá olókun A sòrò dayò Eléri ìpín Ìbíkéjì Elédùmarè Òrúnmìlà akéré finú sogbon A gbáyé gbórun Olóre mi àjíkí Okìtìbíri tí npa ojó ikú dà Opìtàn Ifè Òrúnmìlà o jíre lónìí tide tide Òrúnmìlà o jire lónìí Bi olóta ti njí nílé Aró Èwí nle Àdó Ká mò ó ká là Ká mò ó ká má tètè kú Okùnrin dúdú òkè ìgbètì Òrúnmìlà ò jíre o Ifá ìwo ni ará iwájú Ifá ìwo ni èrò ìkeyìn Ara iwájú náà ló kó, erò ìkeyìn l'ógbón Ifá pèlé o Okùnrin Àgbonnìrègún Oluwo àgbáyé Ifá a mo òní mo òla A rí ìhín rí òhún Bí oba Edùmarè Òrúnmìlà tíí mo oyún inú ìgbín Ifá pèlé o, Èrìgì a bo la Ifá pèlé o, Okùnrin dúdú òkè ìgbètì Ifá pèlé o, Meretelu Nibi tí ojúmó rere ti nmó wa Ifá pèlé o, omo Eníre Ìwo ni eni nlá mi Olooto Ayé Ifá pèlé o, omo Enìre Tí nmú ara ògìdán le Oyín torí omo rè Ó sá wo inú kókó igi Edé fírífírí torí omo re Ó sá gun òkè àjà Òrúnmìlà tí orí mi fo ire Òrúnmìlà ta mí lóre A gbeni bí orí eni A jé ju òògùn lo

description

oriki

Transcript of Ifa

  • If

    Ork If (Recitada en el momento de consulta, para que If oriente al adivino) rnml Ajn If olkun A sr day Elri pn bkj Eldmar rnml akr fin sogbon A gby gbrun Olre mi jk Oktbri t npa oj ik d Optn If rnml o jre ln tide tide rnml o jire ln Bi olta ti nj nl Ar w nle d K m k l K m k m tt k Oknrin dd k gbt rnml jre o If wo ni ar iwj If wo ni r keyn Ara iwj n l k, er keyn l'gbn If pl o Oknrin gbonnrgn Oluwo gby If a mo n mo la A r hn r hn B oba Edmar rnml t mo oyn in gbn If pl o, rg a bo la If pl o, Oknrin dd k gbt If pl o, Meretelu Nibi t ojm rere ti nm wa If pl o, omo Enre wo ni eni nl mi Olooto Ay If pl o, omo Enre T nm ara gdn le Oyn tor omo r s wo in kk igi Ed frfr tor omo re s gun k j rnml t or mi fo ire rnml ta m lre A gbeni b or eni A j ju gn lo